Check out our online
volunteering database
  
home we need volunteers I want to volunteer training and consultancy managing volunteers about volunteering

about us
contact us
news
events
volunteering stories
volunteering facts
not linked yet
downloads
links
membership
volt
European Voluntary Service
Vol4all Inclusive Volunteering
Ireland InVOLved
Safeguard

 

 

FIFI ASIKO SILE FUN IRANLOKIO ORILE-EDE-YI
Enikeni ni o lee fi asiko re sile lati se ise iranlono fum ilu. Kii se dandan pe o gbado je omode tabi agbalagba, olamrim labi obinrin, abarapa tabi alaaboara, enti o nise louro tabi enifi ko ni. Olukuluku ni o ni ohin ti o lee se. Fifi askio eni sile ni anfaani tire. Ni orile-ede Ireland, fifi asiko eni sile tumo si:
“Fifi asiko sile lati lo ara eni fun anfaani afailu adugbo, tabi fum enileeni. O je ohun ti eniyan fe se lati okan wa, sa ko si si ouro sisan fun ise ti olunware ba se. Sugbon awon owo gba ma binu lee w’aiye lori awon inguro icekeeke ti o ba w’aiye lenu ise.”

ARA AWON ANFAANI TO KIA NIBE NIYI

• Anfaani lati ni I’mo siwaju sii
• anfaani lati se awari ise asela eni
• Kiko eko ati nini imo itiun
• Sise iralowo
• Anfaani lati gba idanileko
• Anfaani lati se ise ti o wu eniyan lat okan re wa
• Anfaani lati imo ason eniyan miran si ni ilu
• Kiko eko nipa asa awon ara orile-ede Ireland.

AWON OHUN TI KO SI ANFAANI RE NIYI

• Ko si owo sisan fun ise ti o ba se
• Fifun ni ni iwe ifinihan gegebi eniti o nseise iranlowo fum ilu
• Ko se ileri owo sisan tabi ajemonu fum ise ri o ba se
• Ko si idanilokanle lati ri awon eto kan gba ni orile-ede yi
• Ko si anfaani idanileko lori ede Oyinbo.
• Ko si anfaani lati ko eniyan bi a ti nko tabi ka iwe
• Ko si aaye fun ibi ti o lee gbe omo si ni asiko ti o ba nsise ilu.

AWON OFFUN TI O GBODO SE AKIYESI RE KI O TO GBA LATI FI ASIKO RE SILE:

• Kini awon ohun tin go ri gba nipa fifi asiko mi sile fun ise iu?
• Kini awon ohun ti mo fe se? Kini awon nkan ti ko wu ni lati se?( Fun apere sise ise pelu awon eniyan mimo juto awon omode arugbo tabi alaabo ara ati awoon is bebe lo.)
• Kini awon iriri ati imo mi ti mo fe lo fum ibiti mo ti fe sise?
• Kini awom ohum ti mo fe ko ati lati mo? Awon iriri mo ni mo fe ni?
• Asiko wo ni mo lee fi sile? (O gbodo ro nipa ojo wo asiko ati wakati wo ni o lee fi sile)
• Nibo ni mo ti fe sise? (O gbodo ronu nipa asiko ati bi o se maa de ibe) Sunsbon ile ise yi lee se iranlowo lor inawo yi.

Ti o ba ni ife lati fi asiko sile lati se ise iranlowo lo si ile idasile ti o nse agbateru eto yi ni adngbo ne ile ise ni won nse ikede ninu iwe iroyin nipa gbigba awon ti o fe fi asiko sile fun ise ilu.

AWON OHUN TI O LEE BA PADE NIBITI O TI FE SISE

Klon lee so pe ki o se awon mkan wonji ti o ba de ile ise ti o ti fe fi asiko sile lati se ise iranlowo.
• Klon lee so pe lci o fi owo si iwe nipa ise iranlowo ti o fe se.
• Klon lee so pe lci o daruko awon meji ti yio je gegebi oniduro fun o.
• Klon lee so pe lci o wa fum iforowanilenuro
• Klon lee so pe lci o gba iwe idanimo was lati odo awon olopa (Iwe yi se patalci paapaa ti of ba fe se ise pelu awon omode odokuntim tabi odobinrin)

Balcanna a fe ki o mo daju pe ohun ti ileise lcan ba beere lee yato si ara won nitorimpe idal ni iselu.

AWON NKAN MIRAN TO O LEE SE

Ti o lco ba ni amfaani lati lee fi asiko re sile banyi boya nitoripe o fe igo ede tabi mo bi a tin se ise kan pato qwon ohun ti o lee se niyi.

EDE KIKO: Ile ikawe apapo ti o wa ni ILAC ati awon ile ilcawe adugbo kaakiri nse idanileko ofe nipa bi a tin so ede. Awon ile ikawe yi ti ran opolopo eniyan lowo lati bori isoro ti o nkoju won nipa siso ati kiko ede titum. Awon akeko labe eto yi tum ni anfaani lati monipa asa oriel-ede yi.
Ile eko ita gbanga ti o wa ni ile ikawe apap ILAC, ni orisirisi eto idanileko okan o jokan. Iwe eri was fum enikeni ti o ba kopa nibi idanileko ara eni yi fm aadota wakati o kene julo labe eto naa.

Fun alaye kikum lori eto yi lo si ile ikawe apapo ti o wa ni opopona Henry, Dublin 1. Ero ibanisoro won ni 01 873 4333.

Download Nigeria (Yoruba) brochure

 
Volunteer in your local county: 
  home | we need volunteers | I want to volunteer | training & consultancy | managing volunteers | about volunteering
about us | contact us | news | events | volunteers in action | downloads | links | membership | VOLT
copyright info | legal information | privacy statement | site map
  7328ms Copyright © 1997-2010 Volunteering Ireland